YORUBA
|
Awon Igbese Akoko Pelu Kristi Clifton Moberg has learned: "Sometimes
|
|
• |
Olayinka Peter
Awon Igbese Akoko Pelu
Kristi
1. Kini/Eniti
Olorun Je
Nitoripe Iwo Oluwa, li oga ju gbogbo aye lo,
Olorun wa
je eni iyanu, Oluranilowo, Oludarijini, eniti o nife wa… a le maa faa lo titi
lati mo bi iru Olorun se je. Sugbon niti eniti O je Bibeli so bi awon awon omo
Ju,
Fun opolopo odun, Konsonati merin
wonyi J-H-V-H ni a n pe ni ona meji
“Y” ati “J” ti a sin lo fun ara won eleyi sele si “W” ati “V”. Awon Ju kii ko Voweli ni
Olorun da ohun gbogbo to yi wa ka, ati awa iseda re li o da lati tun maa da. Sugbon ninu
Olorun ni
ipa pupo ninu gbogbo isele itan aye. Loni ari ipa re
lori awon orile
Olorun a ma gbe ibi giga ni awosanma, eyini ninu Orun ti a ko ri. Bee ni Olorun ko jina lati gbo adura wa boya eyi ti a fo lohun tabi ti o ngbe inu wa. Olorun ngbe inu Okan. Halleluyah.
2. Ohun ti Olorun Jo
Emi o si je Baba fun yin, eyin osi je Omokunrin mi ati Omobinrin li Oluwa Olodumare wi. 2 Korinti 6:18
Sugbon a saa li ogbe nitori irekoja wa, a paa li ara nitori aisedede wa, ina alaafia wa wa lara re, ati nipa ina re lia fia mu wa lara da. Aisaya 53:5.
Bi Olorun tiri gan-an ni a fe ki awon eniyan je, olooto, onife, olutoju, eniti kii se wobia, ti kii hu iwa ipa, onisuru, eni rere si awon eranko, enididara ninu ogba, onireti, to kun fun orin, olododo, olooto, ti o pe ni Oro ati ise, eni ti n farable gbo, apa ofin mo. Awon amuye re ko li opin. O ti fi ara re han fun opolopo odun bi eni iyanu fun egbegberun eniyan ti ngbe aye won fun Kristi, Omo Olorun, fun opolopo odun.
Olorun ko i ti gbe aye pelu eniyan ri. O ran Omo Re nigbakan ri eniti atipase Maria ati Josefu bi, sugbon Jesu yato si gbogbo omo ti a ti bi tele ri nitori Wundia lo bi laisi ibasepo okunrin rara. Nipataki Jesu je omo Olorun. Bi Olorun ko tile gbe aye oti ran omo re wa ri ko si tun ni ran wa mo. Gbogbo ireti wa ni lati wa pelu Jesu. Ohun ni ona si igbala, ti o si mu wa yato si gbogbo esin miran, nitori ani Olorun nipase Emi Omo re ti n gbe inu wa. Idi niyi ti a fi gbodo dagba si nipa didi oniwatutu, onife, olutoju eni, enirere ati beebee lo nitori awon abuda Kristi nbe ninu wa. Eleyi ti pase adura tooto wa ninu eyiti a beere lowo Baba lati mu wa dabi omo re. O je ohun iyanu!
Pelupelu, anfaani ati ni Kristi ninu wa ko rorun fun Olorun lati mu ki o sele laye wa, eyi lo mu ki ayanfe Olorun ki o fi ipo re lorun sile lati re ara re sile nipa wiwa si aye lati gbe bi eniyan fun odun metlalelogbon. Ni akoko yi kanna a pon Jesu loju leyin opo ise iwosan, ipese ounje ni opolopo igba. Leyin opolopo iya naa, oku lori agbelebu ti ijoba Roomu ri, eje iyebiye ni si san jade. Nje Jesu ti dese ri?. Rara. Nje o ti bu Olorun ki o to kuro lorun?. Rara. Nje Jesu ja ole bi?. Rara, Jesu to je eni mimo, enipipe ati looto eniyan. Ati nitori ijemimo re, eje iyebiye ati ipalara re je irubo fun ese gbogbo ara aye.
Gbogbo eyi sele nigba pipe seyin. Iru irubo ati etutu bayi ko sele mo. Olorun ti rii pe agbara to wa ninu irubo ti Jesu ti se ni egberun odun meji, seyin si wa laaye gege bi ona si ominira kuro ninu ijiya ti oto si wa nipase ese. A bo nitori ohun gbogbo ti Jesu se fun wa. (Titu 3:7).
3. Ohun Ti Olorun N Reti Lowo Wa
Ibukun ni fun awon tin pa idajo mo, ati eniti nse ododo nigbagbogbo (Saamu 106:3).
Fi gbogbo aya re gbekele Oluwa, ma si se te si imo ara re. Moo ni gbogbo ona re. Oun o si ma to ipa ona re. (Owe 3:5 – 6).
Eyin mo eyi, eyin ara mi olufe. Sugbon je ki Olukuluku enia ki o maa yara lati gbo, ki o lora lati fohun, ki o lora lati binu. Nitori ibinu enia ki isise ododo Olorun. (Jakobu 1:19-20).
Mase fawo ire sehin kuro lodo eniti ise bi o ba wa
li agbara owo re lati see (Owe
Olorun fe
ki a ni iwa pele, ki se ki a
4. Iyipada Wa
Oro Kristi ti a ngbo, ti a fihan to si tun ye wa, ti a si gbagbo ninu okan wa, igbagbo yi wa nipase awon oro Kristi. (Roomu 10:17)
A o we o kuro ninu egbin pelu omi mimo kuro ninu orisa li Emi yo we o. Okan titun li Emi yoo fifun o. emi titun lie mi yoo fi ropo okan okuta, n o si fun o ni okan eran dipo re (Ezekieli 36: 25-26).
Ti a ba rin li ona ti Kristi ti je Baba imole, ti a si ni ibasepo pipe pelu re nigbana ni a we ese wanu kuro nipa eje Jesu Kristi (1John 1:7).
Ole ti o ba wa nibe ko ma jale mo, Ogbodo se
ise mimo pelu owo re. laipe yo si le se iranwo fun awon
alaini (Efesu
Igbala Olorun ti fara han gbogbo eniyan. O ko wa lati korira iwa ibi ati ifekufe, ero buburu ati gbogbo
ohun ti aye fe. A ni lati gbe igbe aye pipe, tooto to
kun fun iwa bi Olorun ni aye buburu yi (Titu
Oro Kristi gbodo siwaju ninu aye wa. Awon oro iye wonyi wa fun
anfaani wa. Lati wa mu wa si oju ise a gbodo ni
igbagbo. Igbagbo wa ti a ba ti fi okan ro mo oro
Bibeli. Jesu ko fi gba
Gbogbo wa ni a ni aseyori kana bi omiran ninu aye, sugbon aseyori wa yoo dara ju pelu Kristi. Oun yoo se ona ti a ko fi nii ru enikeni je. Nipataki, Oun yoo ran wa lowo de ipele ti a ko ro pe a le de ti a o fi le maa dupe pe o seun fun Emi re ninu wa.
Ilepa ti kii ye nipa ati fi aye wa se ohun pataki yio wa, awa gan yto ni ayo iwenumo lati inu
odo okan wa, iwa ati ise wa yoo ma yo toka si mimo, ona 5ti Jesu fe fun wa niyi.
Jesu ni ayo lati je omo Olorun laye, beeni o se ye fun
awa naa lati maa yo. A je ebi
5. Ibunkun Ti O wa ninu Jije Kristieni.
Alabunkun fun ni eni ti o ni iberu Olorun ti o si nrin
ni ona Re, yio je ninu ise owo re pelu ayo nigbati yoo si dara fun un. Aya re yoo je igi eleso fun ninu ile re.
Awon omo rere bi eso olifi yi tabili re ka. Ati Emi? Emi o si dabi igi
olifi tutu to ni gbongbo ni ile Oluwa. Ninu
Igbese eniyan ni aabo to daju nigbati a ba dari re lati odo Oluwa, oun si ni inu didun ninu re. Saamu 37:23.
Ileri yi ni Jesu fun wa: Iye ayeraye 1 Johannu.
Iberu Olorun nmu ojo aye eniyan gun, beeni ojo eniyan buburu ni a o ke kuro. Owe.
Ojo miran inu eniyan maa n dun lai
si idi
O ko ni lo ati maa wadi otito kiri ninu awon esin miran nigbati o ba ti ri otito ninu Jesu ti Majemu Titun. Nitori lati inu Re ni iyonda re ni kikun ti bere ninu gbogbo ohun ti o n ko nipa Olorun.
Ona iye ti Jesu ko awon ti o koko telee wa ninu Bibeli. Awon ese bibeli yi je ayo ati okun re. Won fun o ni ireti pipe lati fi okun fun ilepa re. Bi a se n mo sii nipa ise wa, iwe kika, ninu eto isuna owo, gbogbo ohun to n sele laye wa yio maa fogo fun Olorun. A si mo pe oseese lati te Olorun lorun.
6. Idanwo Ati Idojuko Lati Inu Aye
E kaa si ayo nigbati a pon yin loju tabi niwalara, ki a si mo pe iponju n sise suuuru, ki a si je ki suuru sise pipe re, gbgogbo iwonyi a mu wa pe, dagba lai s’alaini ohunkohun. Jakobu 1:2-4.
Awa ni olori alufaa ti n benbe fun ailera wa. O ti dojuko iru idanwo bee ri lai dese Heberu4:15.
Igbeyawo je ouhun ti o lola, akete si gbodo je alaileeri. Awon agbere ati pansaga ni Oluwa yoo da lejo. Heberu 13:4.
Nibi ti ojukokoro, owu ati ilepa buburu ba wa, nibe ni awon iwa buburu wa, lati si ni lona, ati lati fa idarudapo. Jakobu 3:16.
Igbekele dabi
oro li aye.
A o ni idi lati maa sise tabi gbe igbese lori awon ero buburu inu okan wa. A ni lati maa se gege bi ofin ti Jesu fun wa lati igba pipe. Jesu ti si apa ti o safihan itewogba wa. Bakanna a gbodo beere iwenumo pelu. A fe wa ni ona mimo yi titi lo. Ogbo Olorun ni lati mu wa dagba ni ona ti aye ko mo. A le mu ero aye kuro lokan wa, sugbon ni ekookan, idanwo to le to buru ju awon ti isaaju lo le wa. Sugbon a ni isegun ninu Jesu. Oun ni Oluso-Agutan wa”. O n pawa mo ninu gbogbo ibi segbe ara Re.
7 . Ileri Olorun Fun Ipamo Ati Ipese
Gbogbo iwapele je sisin Olorun re, Oun bunkun ounje ati omi re. “Emi yoo si mu aisan jinna sio” Eksodu 57:25.
Yio ranse lati orun lati gba mi ninu idojuko to je egan fun mi; Oluwa ran aanu ati otito re wa. Saamu 57:3.
Pelu Olorun, a lee se ohun gbogbo pelu okan akin nitori Oun lo mu apon ota subu. Saamu 60:12
Nigbati ona eniyan ba wu Olorun, yoo mu ki awon ota re maa gbe ni irepo pelu re ni alaafia. Owe 16:7
Ninu irin ini nibiti wahala gbe po, nina owo otun agbara re, Olorun, tako awon ota lati gbani la lowo won. Saamu
Ni siso wa di eniyan, Oluwa yoo mu awon ota wonni ti o dide sio gba isubu, won a sis a, won a fon kaakiri niwaju re. Ditaronomi 28:7
Awon eni ibi li a o pare lakoko wahala, sugbon awon olodo ni igbekele botile je iku wa ni itosi. Owe
Iwe eko yii ti n so fun nipa igbe aye igbagbo Kristeni. Ohun ti igbagbo wa koko duro le ni ohun ti Kristi fi fun wa (lori agbelebu). Bakanna, ileri re nipa orun ati aye ti awa yi. Awon ileri yi sise iju igba ti o lo laye lo, yoo si tun wa titi lae (ayeraye). Ti a ba se amulo awon ese oro bibeli ti awon ajiya fun Kristi ni bi egberun odun meji seyin, awon oro Jesu ti won mu lo na si ni agbara titi di oni yi aye wa.
O le akiyesi wo pe awon ti ko si ninu Jesu n see bi idan. Won ki fi igba gbogbo ni ireti bo tile je wipe won ntiraka. Sugbon awa ni ifokanbale ninu aya wa, ninu awon alaafia ti Olorun seleri fun wa ni to si n sise fun eyi to dara li aye wa.
8. Jije Akeko Bibeli Laisinmi
Olorun yoo se asepe eso odo Kristi ninu re si iyin ati ogo oruko re. Filipi l: 11
Masi se aikasi, tabi gba irewesi laye nigbati Oluwa n ba o wi. Mase sa fun iresile nigbati o n ba wi. Nitori gege bi baba ni o wa lati dabo boo ninu idajo ti n bo sori aye. Heberu 12: 5-6, 1 Korinti 11: 32
Opolopo ti so di asa won lati ka,
ki o si ye won, ki won si fi sinu emi won orisirisi eda ese
oro Olorun ni ojoojumo. Won haa sori won si lee maa tun so nigbati bibeli ko si ni itosi won. Fun awon elomiran oro yi je ounje fun
okan won ni kika ori
Bibeli kika lojoojumo ni lati lo pelu adura, Jesu fun awon omo ehin Re ni itoni
adura ojojumo “Baba wa ti n be ni orun, ki a bowo fun Oruko re, ki ijoba re de,
Nini oluko lee mu oye wa dagba ni kankan nipa mimu lati orisirisi oun ti won ti ko lati Majemu Lailai ati Majemu Titun ti Kristi ati ijo akoko fun wa lati ni imo nipa eto Olorun fun aye ti a se akosile re ninu bibeli. Nipataki yan oluko laarin egbe re ti o le pin oye ati imo ninu iwe mimo.
Eniyan ki ka bibeli ni odun
Iwe Mimo so nipa
ojo ogbo. Igbagbo Kristeni ti a ni je ti igba
pipe. Opolopo lo ti rin ni aye yi ri won si gbagbo bii
awa, ani siwaju re.
9. Ipejo Awon Ara Ni Ijosin Fun Olorun
Gege bi ayanfe ti a ya soto, bo ara re pelu aanu. Je oninututu, oniwapele to ni suuru. Fara da ikunsinu tabi aleebu ti oni si elomiran. Ranti Oluwa tii dari ji o, o ni lati dariji. Kolosse 3: 12-13
E maase rere si ara yin. Eyi se pataki nitori
Eni ife to peye si ara yin, e ko ibi, e di ohun rere mu sinsin, e fi owo fun ara yin ninu eyi ni ayo pipo wa. Roomu 12: 9-10
Jesu so fun awon omo eyin re “Ofin mi titun fun yin niyi. Efe ara yin bi mo ti fe yin “Eyi fi han pe omo eyin mi niyin,
wipe e fi
Nipa apeere ati igbe aye wa, opo eniyan ni yoo fe sin Olorun. Nje o le mu iwa rere Re lo? Nje o ni ero rere si awon ti ko tii di eni igbala? Se oun fun awon eniyan ni awon amoran to ti inu Bibeli jade bi? N je o ni igboya lati polongo gege bi ajogun ibukun aaye? N je o fe lati gbadura si Baba ki o si pari adura re pelu oruko Jesu?
Se adura re
Nife, ki o si feran bi Kristi ti fe wa. Ninu Bibeli, ero ati omoleyin ni
Jesu feran, nisiyi Kristi fe wa lati orun wa nipa ti Baba wa orun. Emi ti gbe inu wa je ti ododo ti o fe ka maa fi huwa si awon
elomiran bi eniti o saanu ati ni
10. Sise Fun Ijoba Orun Ni Diduro De Igbasoke Kristi
Ara, awa we ara wa mo si iwenumo ti Kristi ti se. O ye wa ko daju sugbon ireti wa daju pe a o dabi Re nigbati aba rii. 1 Johannu 3:2-3.
Olorun, o ti ko mi lati igba odo mi, mo si so
ti iyanu Re titi di oni. Mase ko mi sile, fun mi laye
titi di igba ogbo mi lati maa rohin agbara re lati
Sa ipa re lati fihan pe ati yan o lati odo Olorun, lati koni laitiju pelu eko to o yee koro. 2 Timotiu 2: 15
Olorun to seleri igbala ki fa seyin; bee ni awa ireti bibo Re Oun si ni awa njewo. Heberu 10: 23
Bi emi Olorun ba n gbe inu re, bi iku tile de, Olorun to gbe Jesu dide laaye nipa Emi yoo ji wa dide pelu. Roomu 8: 11
Ni ojo ola,
Kristi yoo de lati wa ko wa lo sorun. Nkan yi yoo sele ni
Maa To Mi Leyin
Jesu pade Philipi o wi fun pe “maa to mi leyin “. Oro Jesu yii ni agbara pupo ti Phiipi si fi di eni igbala. Oun naa si jeri fun Natanieli “Awa ti rii, eniti Mose so ninu ofin ati
ti awon woli kowere”. Jesu ti Nazareti, omo Josefu.”
Sugbon Natanieli ko gbagbo otun beere “n je ohun rere
Boya a ti roo o
pe “Wa wo Jesu!” Pelu idahun
re ni
N je o duro bi?
abi o n siye meji? O daa je ki n salaye die fun nipa
Jesu ati
Jesu…
Eyi ni ijewo ese re, Bayi kaa soke gege bi ijewo igbagbo ninu re
“Mo gbagbo ninu re Jesu. Mo gbagbo ninu aye re nihin, Iku re lori agbelebu nibiti eje ailese re ti san fun aye. Mo gbagbo
ninu ayeraye ti Olorun ti fun o. iwo Omo Re kan soso, nigbati o gbe o dide kuro
ninu oku O si fi agbara ajinde tutun fun O, eyi ti o kan aye mi pelu. Mo gbagbo
pe mo ti gba idarijin fun ese mi nitoripe o n gbo adura
mi lorun bayi legbe Baba olufe. Mo fi igbekele mi sinu awon ileri ti o ti se fun
mi awon oro lati inu Bibeli to wipe “Gbogbo agbara lorun ati ni aye li a ti
fifun mi” Matiu 28:18. ‘Sugbon gbogbo awon ti o gbaa (ani
Aposteli Poolu kowe si ijo majemu titun awon kristieni ti ngbe ni Efesu “Eyin paapaa, gbeke lee (Jesu oluwa) nigbati e gbo oro otito ti ihinrere igbala. Nigbati e ti fi igbekele yin fun, eyiti a fi edidi ileri Emi mimo di gegebi eje ajogun wa titi di ojo ti Olorun yoo sa sepe irapada ohun tii se tire. Efesu. 1:13-14
Nigbati Jesu ti pe omo ogbon odun, ijo Re bere pelu ohun nikan. Oluso Agutan rere. Laisi omo ijo, eyi ni ibere kekere sugbon o so otito ti Olorun Baba, ti Emi Mimo ati nipa ara re tii se Kristi. O soro oorun o si se ise iyanu nipa agbara Emi mimo. Nipa sise eyi O ri anu gba ni oju awon eniyan. Pelupelu igbe aye ti ki se ti imotara-eni-nikan
Bi o ti gba Jesu sinu aye re, pelu
awon oro Olorun ti a gbin sinu re, ibere igbe aye ninu emi re si kere gege bi
ijo Kristi ti koko kere . Sugbon yoo maa dagba gege bi o ti yonda aye ati akoko
fun Oluwa. Pelu Jesu ninu okan re o ki yio fee lati pada sehin si igbe aye atijo.
Be naa si nip e o ma bo ogbologbo okunrin ni sile fun igbe aye titun ninu
Kristi. Paul kowe si ijo Efesu wipe “Emi mimo ni edidi
--------------
Living Grace Christian Mission
O dara lati ka akosori awon iwe Bibeli ni sise n tele gegebi ati ri ninu Majemu Titun. Matiu, Marku, Luku ati Johannu ni a mo si iwe ihinrere merin awon naa si ni iwe merin akoko. Ise ni a mo si Ise awon Aposteli (awon aposteli ni awon momo ehin akoko nigbati a to ji Jesu dide). Roomu ati titi de Heberu ni awon iwe ti Poolu Aposteli ko, lati Jakobu titi de opin Bibeli ni awon iwe ti awon arakunrin Jesu, Peteru, Johannu (omo ehin) ati Juudu.
| (a) | (b) | |
| Matiu | Timotiu 17 | |
| Marku | Timotiu 2 | |
| Luku | Titu | |
| Johannu | Filemonu | |
| Ise | Heberu | |
| Roomu | Jakobu | |
| Korinti 1 | Peteru 1 | |
| Korinti 2 | Peteru 2 | |
| Johannu 1 | ||
| Efesu | Johannu 2 | |
| Filipi | Johannu 3 | |
| Kolosse | Juudu | |
| Tesalonika 1 | Ifihan | |
| Tesalonika 2 |